Moyugba olorun, moyugba achukua,moyugba
olordumare,moyugba ilogguere,moyugba
ochun.
Omi tuto, ona tuto,tuto nene,tuto
larogba,tuto laweikoko.
Omi fun olorun,omi fun eggun ara onu
Igba she bogbo oulo tokun, igba she bogbo
iyalosha, igba she babalosha,iworo tokun,
ke timbeloro , ke timbelese olordumare
Ashe baba, ashe yeye,ashe orumale
yikotun,ashe orumale yikosi, ashe mi
iyalosha Nancy alan larrinaga omo obbatala
alamito, ashe mi oyugbona clara omo oya
olladdina,ashe mi iyatobbi Raquel medina
glez omooggun oggunfumito,ashe alburemi
omara oliva medina omo obbatala
babalarde, ashe bogbo osha,bogbo oricha,
bogbo eggun aronu, ashe orula, ashe to,
ashe bo, to ebban echo.