Thanks to visit codestin.com
Credit goes to www.scribd.com

0% found this document useful (0 votes)
80 views4 pages

Word For Programme

The document outlines the officiating ministers and the order of service for a church event, including hymns, prayers, scripture readings, and special songs. It details both the worship service and the interment procedures, with specific hymns and prayers listed in both English and Yoruba. The structure emphasizes community involvement and spiritual reflection throughout the ceremony.

Uploaded by

ademmalconcept
Copyright
© © All Rights Reserved
We take content rights seriously. If you suspect this is your content, claim it here.
Available Formats
Download as DOCX, PDF, TXT or read online on Scribd
0% found this document useful (0 votes)
80 views4 pages

Word For Programme

The document outlines the officiating ministers and the order of service for a church event, including hymns, prayers, scripture readings, and special songs. It details both the worship service and the interment procedures, with specific hymns and prayers listed in both English and Yoruba. The structure emphasizes community involvement and spiritual reflection throughout the ceremony.

Uploaded by

ademmalconcept
Copyright
© © All Rights Reserved
We take content rights seriously. If you suspect this is your content, claim it here.
Available Formats
Download as DOCX, PDF, TXT or read online on Scribd
You are on page 1/ 4

OFFICIATING MINISTERS

1. BISHOP CHAPLAIN J.O. OLUSEYE

2. REV. DR. S.B. MORADEYO

3. REV. (DR.) A. OLAOLUWA

4. PASTOR CHAPLAIN OLUDARE AMOS

5. REV. MRS. OYERO TAIWO

6. REV. MRS. ALICE MORADEYO

7. L/EVANG. MRS. ADEBOWALE

8. ELDER D. OYERO

9. ELDER RASAK JINADU\


ORDER OF SERVICE / ETO ISIN
1. Call to worship - Ipe si Isin
2. Hymn HC 176 - Orin 176 – Jesu ye titi aye
3. Thanksgiving Prayer - Adura Ope
4. Scripture Reading - Bibeli Kika
5. Biography - Itan Igbesi Aye Iya Wa
6. Special Song 1 - Orin Pataki Kinni
GWCM Igboora
7. Message - Iwaasu
8. Special Prayer for the Families - Adura Pataki fun Awon Ebi
9. Poem - Ewi
10.Special Song - Invited Choirs
11.Announcements - Ifilo by General Sec.
12.Special Gift for the Church - Ebun Pataki fun Ijo
13.Heart of Appreciation - Okan Idupe
14.Closing Hymn 328 - A o Pade leti odo 328
15.Closing Prayer - Adura Ipari Isin
16.Benediction - Oore Ofe
17.Recessional Hymn 413 - Jerusalem Torun, Hymn 413

INTERMENT / SISIN OKU


1. Hymn 413 - Orin 413 – Jerusalem Torun
2. Reading of the Bible - Kika Oro Olorun
3. Committal - Sisin Oku
4. Prayer - Adura
5. Closing Hymn 425 - Orin Ipari 425
Ma sun lo, Olufe, sa ma sin mi

ORDER OF SERVICE / ETO ISIN


1. CALL TO WORSHIP - IPE SI ISIN
2. HYMN HC 176 - ORIN 176 – JESU YE TITI AYE
1. Jesu ye, titi aiye 4. Jesu ye; eyi daju
Eru iku ko b ani mo; Iku at’ipa okunkun
Isa ye; nitorina Ki y’ o le y ani kuro
Isa oku ko n’ipa mo Ninu ife nla ti Jesu
-Alleluya! -Alleluya!
2. Jesu ye, lat’ oni lo 5. Jesu ye; gbogbo ‘joba
Iku je ona si iye; L’orun, li aiye di Tire;
Eyi y’o je ‘tunu wa E je ki a ma tele
‘Gbat’akoko iku ba de Ki a le joba pelu Re
-Alleluya! -Alleluya!
3. Jesu ye, fun wa l’O ku;
Nje tire ni a o ma se;
A o f’ okan funfun sin,
A o f’ ogo f’ Olugbala
-Alleluya!

3. THANKSGIVING PRAYER - ADURA


4. SCRIPTURE - BIBELI
5. BIOGRAPHY - ITAN IGBESI AYE IYA WA
6. SPECIAL SONG 1 - ORIN PATAKI KINNI
GCWM IGBOORA
7. MESSAGE - IWAASU
8. SPECIAL PRAYER FOR THE FAMILIES - ADURA PATAKI FUN AWON EBI
9. POEM - EWI
10.SPECIAL SONG - INVITED CHOIRS
11.ANNOUNCEMENTS - IFILO BY GENERAL SEC.
12.SPECIAL GIFT FOR THE CHURCH - EBUN PATAKI FUN IJO
13.HEART OF APPRECIATION - OKAN IDUPE
14.CLOSING HYMN 328 - A O PADE LETI ODO

1. A o pade leti odo, 3. K’a to de odo didan na,


T’ ese angeli ti le, A o s’eru wa kale;
T o mo gara bi kristali Jesu yio gba eru ese
Leba ite Olorun? Awon ti yio de l’ade
A o pade l’eti odo, 4. Nje leba odo tutu na,
Odo didan, odo didan na, A o r’oju Olugbala
Pel’awon mimo leb’odo Emi wa ki o pinya mo,
T’ o nsan leba ite na Yio korin ogo Re.
2. L’eti bebe odo na yi,
Pel’ Plus’aguntan wa,
A o ma rin, a o sin.
B’ a tin tele ‘opase Re
15.CLOSING PRAYER - ADURA IPARI ISIN
16.BENEDICTION - OORE OFE
17.RECESSIONAL HYMN 83 - ORIN AKOJADE

INTERMENT / SISIN OKU


1. HYMN 413 - ORIN 413 JERUSALEM TORUN
1. Jerusalem t’ orun 3. Orun Ki ran nibe,
Orin mi, ilu mi! Beni ko s’osupa;
Ile mi mba ku, A ko wa iwonyi
Ekun Ibukun mi; Kristi n’imole ibe.
Ibi ayo! Etc.
Ibi ayo! 4. Nibe l’Oba mi wa,
Nigbawo ni, T;a da l’ebi l’aiye
Ngo r’oju re, Angeli nkorin fun.
Olorun mi? Nwon si nteriba fun.
Ibi ayo! Etc.
2. Odi re, ilu mi,
L’a fi pearl se l’oso
Lekun re nadan fun ‘yin,
Wura ni ita re!
Ibi ayo! Etc.
2. READING OF THE BIBLE
3. COMMITTAL
4. PRAYER
5. CLOSING HYMN 425 MA SUN LO, OLUFE, SA MA SINMI

1. Ma sun lo, olufe, sa ma sinmi, 4. Titi orun ajinde y’o di yo


F’ori re le aiya Olugbala; Tia won oku njesu y’o died;
A fe o, sugbn Jesu fe o ju; Ti on y’o de ninu ola nla Re,
O di owuro o! O di owuro o!
2. Orun re dun bi orun omode 5. Titi ewa orun y’o je tire
B’o si ji ekun ko si fun o mo, Ti iwoo ma tan ninu ogo
Isinmi t’o daju n’sinmi re, Ti Oluwa y’ o fi de o l’ade,
O di owuro o! O di owuro o!
3. Titi okunkun aiye y’o fi tan, 6. O d’owuro s ani, olufe mi,
Titi a o fi ko ikore wo ‘le Atun fere ri ‘ra ba n’ibiti
Titi oye aiye yio fi la, Ipinya ati ituka ko si,
O di owuro o! O di owuro o!

7. Tit’a o fi pade niwaju ite,


Nin’aso igunwa awon Tire
Titi a o fi reran kedere,
O di owuro o!

You might also like