Order of Service Eto Isin
1. Praise & Worship 1. Orin Iyin
2. Opening Hymn- 510 2. Orin Ibere Isin 510
(Bride’s Procession) (lyawo Yio Wole)
3. Opening Prayer 3. Adura Ibere Isin
4. Scripture Reading 4. EKo KiKa
5. Charge and Declaration 5. Ibere Saaju Isowopo
6. Exchange of Vows 6. Sise Adehun
7. Giving and Receiving of 7. Fifun ati Gbigba Bebeli
Holy Bible Mimo
8. Prayer for the Couples 8. Adura Kikun fun awon ti a
9. Warning Dapo
10. Anthems: Church Choir
11. Sermon 9. Ikilo
12. Prayer 10. Orin Adako: Akorin ljo
13. Signing of Marriage 11. Iwaasu
Certificate 12. Adura Lehin Iwaasu
13. Fifi Owo si Iwe Eri
14. Thanksgiving Gbeyawo
15. Presentation of Marriage
Certificate 16. Ifilo
17. Orin Ipari Isin- 626
16. Announcement 18. Orin Alleluia
17. Closing Hymn 626 19. Ore Ofe
18. Hallelujah Chorus
19. Benediction
1. PRAISE WORSHIP 1. ORIN IYIN
2. BRIDAL PROCESSION 2. ORIN IBEERE ISIN CACGHB 510
HYMN510
1. The voice that breathed o’er 1. Ire t’a su ni Eden
Eden Nigbeyawo kini;
That earliest wedding-day, Ibukun ta bukun won
The primal marriage blessing Owa sibe -sibe
It hath not passed away.
2. Sibe titi di oni
2. Still in the pure espousal
Nigbeyawo Kristiani:
Of Christian man and maid
The holy three are with us, Olorun wa l’arin wa,
The threefold grace is said. Lati sure fun wa.
3. Fordower of blessed children, 3. Ire ki won le ma bi
For love and faith’s sweet sake, Ki won ko si ma re
For high mysterious union Ki won ni ‘dapo mimo
Which nought on earth may Tenikank’yo le tu.
Break.
4. Be present, heav’nly father, 4. Ba wa pe, Baba orun,
To give away this bride, Fobirin yi foko
As eve thou gav’st to Adam Bi O ti fi Efa fun
Out of his own pierced side. Adam I’ojo kini.
5. Be present, gracious saviour, 5. Ba wa pe, Immanuel;
To join their loving hands,
Si so owo won p0,
As thou didst bind two
Natures Beda meji ti papo
In thine eternal bands. L’ara ijinle Re
6. Bepresent, holy spirit,
Tobless them as they kneel, 6. Ba wa pe, Emi mimo;
As thou for Christ the Fibukun Re fun won;
Bridegroom E Si se won ni asepe
The heav’nly spouse dost seal
Gege b’O ti ma nse.
7. O spread thy pure wings oer
Them! 7. Fi won s’abe abo Re
Let no ill pow’ r find place, K’ibi kan ma ba won;
When onward through life’s Gba won npara ile Re
Journey Ma toju okan won.
The hallow’d path they trace.
8. To cast their crowns before 8. Pelu won loj’ aye won
Thee, At’ oko at aya;
In perfect sacrifice, Titi won o d’odo Re
Till to the home of gladness Nile ayo l’orun.
With Christ’s own bride they
Amin
Rise.
Amen.
3 OPENING PRAYER 3. ADURA IBERE ISIN
4. SCRIPTURE READING 4. EKO KIKA
5. CHARGE AND DECLARATION 5. IBERE SAAJU ISOWOPO
The officiating pastor will then say:
Dearly beloved, we are gathered Here Ngbana ni Alufayio wipe: olufe owon,
before God and His Congregation, to awa pejo nihinyi, niwaju Olorun ati li ijo
j o i n t o g e t h e r O L U WAT O S I N yi lati da okunrin yi SIMON ADEBIYI
ABOLANLE AND ADEBIYI OY E T O L A AT I o b i r i n y o u
OYETOLA in a Holy matrimony, OLUWATOSIN ABOLANLE IGE
w h i c h i s a n H o n o u r a b l e e s t a t e, Po ni igbeyawo mimo, ti se ipo to ni ola,
instituted by God himself, signifying us ti Olorun ti sa sile saju 1subu eniyan,
the Mystical union between Christ And
isele wa, nigbati o lo si ibi igbeyawo ni
His Church. This Holy estate Christ
both honoured and beautified with his Kana ti galili, to si se ise iyanu akOse re
presence at the wedding in canal first nibe. Eyi naa ni iwe mimo so wi ape o li
Miracle. It is also commended by ola larin gbogbo eniyan, nitori,
Apostle Paul to be great honour among igbeyawo ki se ohun ti a kubuohun ta fi
all men. It is therefore Nothing to be sere, lati ma te ifekufe eniyan lorun, bi
rushed into, Undertaken or instituted eranko ti ko ni ye ninu, sugbon towo
lightly To satisfy our carnal lusts and towo, toye toye, tero tero, ni pele pele ati
appetites like brute beast that Have no
understanding but Undertaken eberu Olorun, ki ama ro bi o ti ye nitori
reverently, discretely, soberly, and in the kini a se da igbeyawo sile?
fear Of God. Carefully consider the
reason for which marriage was ordained IDI KINI: A da sile fun ajumo kegbe
iranlowo ati itunu ti o ye ki enikeni ki o
FIRSTLY: It was ordained for the oni lodo enikeni ni irora ati niipoju.
mutual companion, help and comfort
the one ought to have for each other in IDI IKEJI: A da sile kiole se idena si ese
prosperity and adversity.
ati ki o le ya ona agbere sile nitoripe iru
SECONDLY: It was ordained as remedy awon ti ki li ebun imaraduro ki won ki o
against sin and to avoid fornication that gbeyawo, ki won kio si pa ara won mo lii
such persons who keep themselves eya Kristi tikoli eeri.
under
Undefiled members of Christ’s Body. IDI KETA: A da sile nitoriti omo bibi ti a
o to ni iberu ati ni eko olorun ati si iyin
T H I R D LY: i t wa s o r d a i n e d f o r oruko mimo re. ipo mimo yi ni awon
procreation of children, to be brought up
in the fear and nurture this holy estate mejeeji yi wa lati da aara won po sinu re,
twvo persons here present have come nitorina bi enikeni bari ohun ikose tooto
can show any just cause, why they may kan nitori eyi ti a ki yio le fi da won po bi
not lawfully joined together, let him not o tto si nipa ofin ki o wi nisinsiyi, bi ko se
speak or else here after forever hold his be, lati oni lo ki o pa enu re mo titi lai.
peace.
(The Pastor’s question to the couple) i (Oluso aguntan yio bere lowo awon
required and charge you as you will mejceji ni iduro)
answer at the dreadful day of judgement, Mo bere lowo eniyan mejeeji, bi on se pe
when the secret of all hearts shall be eyin ni yio dahun li ojo ti o li eru pupo,
disclosed, that if either of you know any
impediment why you may not be nigbati ohun ikoko gbogbo okan eniyan
lawfully joined together in matrimony, yoo si sile, bi enikan ninu eyin mejeji ba
you may now confess it, for be it known mo ohun ikose tooto kan, ti ki yio je ki a
to you that so many as are joined da yin po ni ti igbeyawo, nitori kio dayin
together| against laid down principles in loju pe iye awon ti a ba da po lodi si bi oro
the word of God are not joined together
Olorun ti la sile fun ni. olorun ko da won
by God and their matrimony is not
lawful. po beni igbeyawo won ki ise nipa ofin.
(Pastor shall say to the man) (Oluso aguntan yio bere lowo okunrin
SIMON ADEBIYI Will you have naa)
OLUWATOSIN ABOLANLE as your
SIMON ADEBIYI iwo feni obinrin yii
wedded wife to live together according
to God’s ordained in the holy estate of OLUWATOSIN ABOLANLE ni iyawo
matrimony? will you love her, honour re, ki eyin ki ojumo ma gbe po gegebi
and. keep her in sickness and health and idasile Olorun, ni po Mimo igbeyawo?
forsaking all others, keep yourself if only
Iwo yoo ma fe, n iwo yo ma tu ninu, iwo
unto her, so long as you both shall live?
yo maa bu ola fun un? Iwo yo ma se itoju
the man shall answer: I WILL BY THE re ngba aisan ati ilera, ki iwo si ko
GRACE OF GOD gbogbo awon elomiran sile ki on si fara
moo oun nikansoso titi a iwon igba
(Pastor shall say to the woman) t’eyin mejeeji yio fi wa laiye?
OLUWATOSIN ABOLANLE you
have SIMON ADEBIYI as your wedded
husband to live together according to
God’s ordinance in the holy estate of Ohun nayio si dahun wipe
matrimony? Will you love her, honour BEENI MOFE, KI OLUWA RAN MI
and keep her in sickness and health, and LOWO
forsaking all others, keep yourself only
unto her, so long as you both shall live?
(Oluso aguntan yoo bere wipe)
The woman shall answer I WILL BY (Oluso aguntan yio bere lowo obinrin
THE LORD GRACE OF GOD naa)
OLUWATOSIN ABOLANLE,
(Then shall the Pastor say)
Who gives this woman to be Married to iwo fe ni okunrin yi SIMON ADEBIYI
this man? , ni oko re, ki eyin jumo ma gbe po gegbi
(The father of the woman shall take her idasile Olorun, ni ipo mimo igbeyawo?
with the right hand and handed over to Iwo yo ma bu ola fun un? Iwo si mo oun
The pastor). nikan soso, ki iwo si ko awon elomiran
6.EXCHANGE OF VOWS sile ki osi fara mo oun nikan soso titi
(The man holding the right hand of the fiwon igba ti eyin mejeeji yio h wal’ aye?
Woman shall say)
S I M O N A D E B I Y I t a k e y o u Obirin na yio dahun wipe:
OLUWATOSIN ABOLANLE to be my E BENI MO FE, KI Oluwa RAN MI
wedded wife, to have and to hold from
this day forward, for better for worse, for LOWO
richer for poorer, in sickness and in
health to love and to cherish, till death do (Oluso aguntan yoo bere wipe)
us part, according to God’s holy
ordinance and there to, I give you my Tani o fi obirin yi fun okurin yi
truth.
Latiniiyawo?
(The woman holding the right hand of The (Baba obinrin na yio fi owo otun re mu yio si
man shall say): ifh le Oluso-aguntan lowo)
I, OLUWATOSIN ABOLANLE take
you SIMON ADEBIYI to be my 6. SISE ADEHUN
wedded husband, to have and to hold
(Okunrin naa yio ji owo otun re di owo
from this day forward, for better for
worse, for richer for pooper, in sickness obinrin naa my, yio si wipe)
and in health to love and to cherish, till E mi SIMON ADEBIYI gba iwo
death do us part, according to God’s OLUWATOSIN ABOLANLE ni aya
holy ordained and there to, I give you my mi, lati ni, ati lati mu, lati oni lo, ti bi re,
truth.
ninu oro ati ninu ponju, ninu aisan ati sni
7. GIVING AND RECEIVING OF ilera lati fe, titi iku yoo fi ya wa, gegebi
HOLY BIBLE idasile mimo Olorun, si eyi, mo fi otito
The pastor shall say: what sight of the mi fun o.
Truth do you have for each other?
The groom shall give the bride the new
(Obinrin naa yio f owo otun re di owo
bible and they shall hold it
okunrin naa mu, yio si wipe emi
The groom shall say after the pastor: OLUWATOSIN ABOLANLE
with this Holy Bible, which is the word gba iwo SIMON ADEBIYI ni oko mi,
of God, I wed you, with my body, I will lati
honour and with all my worldly goods, I
will endow you in the name of the father,
Son and of the Holy spirit. Amen.
8. PRAYER FOR THE COUPLE ni, ati lati mu, lati oni lo, ti bi re,
The pastor shall join their hands together and ninu oro ati fe, titi iku yoo fi ya
say. swa, gegebi idasile mimo Olorun, sieyi,
Those whom God has joined together let
no man put asunder: for as much as mo fi otito mi fun o.
SIMON OYETOLA and
OLUWATOSIN IGE have agreed 7. FIFUN ATI GBIGBA BIBELI
together in holy wedlock and have MIMO
witnessed the same before God and this Alufa yio bere wipe kini ami otito ti eni
congregation and have given and pledge
their truth to each other the have E fun ara yin?Nigba na ni okunrin na yi
declared the same by giving each other fi bibeli titun fun obinrin naa, awon
the holy bible which is the word of God mejejiyio si dimu
and everlasting witness by joining and
hand,I pronounce that they should be Okunrin na yio si ma wi tele Alufa pe:
living together as husband and wife.
Bibele Mimo yi ti se oro Olorun ni mo fi
9. WARNING ba ogbeyawo, ara mi li emio fi bu ola fun
o ati ohun aye mi agbogbo ni emi o maa
fi ke o li oruko Baba ati niti Omo ati niti
emi Mimo, (Amin).
8. ADURA KIKUN FUN AWON
TIADAPO
Ngba na ni Alufa yio da owo otun won
po,yio si wiþe:
Awon eni ti Olorun ba ti sopo sokan ki
enikan ki o ma se ya won. Nje bi SIMON
OYETOLA ati OLUWATOSIN IGE
tijumo fi ohun sokan ni igbeyewo mimo,
ti won si jewo eyi niwaju Olorun ati ijo
yi, ti won si fi eyin han ni fifun ra won, ni
Bibeli Mimo ti se oro Olorun ati ileri
ayeraye ati ni idapo, mo so wipe Ki won
maa gbe po li OKO ati AYA lati oni lo, ni
oruko Baba ati Omo ati Emi Mimo.
Amin.
9. IKILO.
10. ANTHEM 10. ORIN ADAKO: AKORIN IJO YI
11. SERMON 11. IWAASU
12. PRAYER AFTER SERMON
12. ADURA LEHIN IWAASU.
13. SIGNING OF MARRIAGE
CERTIFICATE 13. F I F I O W O S I I W E E R I
IGBEYAWO.
14. THANKSGIVING
15. PRESENTATION OF 14. IDUPE IGBEYAWO.
MARRIAGE CERTIFICATE.
15. GBIGBA IWE ERI IGBEYAWO.
16. ANNOUNCEMENT
16. IFILO
17. ORIN IPARI ISIN
17. CLOSING HYMN
CACHB 626
CACGHB 626
1 . Through the love of God our
saviour, 1. Nipa ife Olugbala,
All will be well; Ki y’o si nkan;
Free and changeless is his favour, Oju rere Re ki pada,
All, all is well:
Ki y’o si nkan;
Precious is the blood that heal’ d us;
Perfectisthe grace that seal’dus; Owon l’eje t’o wo wa san;
Strong the hand strech’d Pipe l’edidi or’ofe;
forth to shield us, Agbara l’owo t’o gba ni
All must be well. Ko le si nkan.
2. Thou we pass through
Tribulation, 2. Bi a wa ninu iponju,
All will be well; Ki y’o si nkan;
Christ hath purchas’d full salvation, Igbala kikun ni tiwa
All, all is well; Ki y’o si nkan,
Happy still in God confiding,
Igbekele Olorun dun;
Fruitful, if in Christ abiding;
Holy, through the spirit’ s Gbigbe inu Kristi l’ere,
guiding, Emi si nso wa di mimo,
All must be well. Ko le si nkan.
3. We expect a bright 3. Ojo ola yio dara,
Tomorrow; Ki y’o si nkan,
All, will be well; Gbagbo le korin n nu ponju
Faith can sing through days
Of sorrow Ki y’o si nkan,
All, all is well; Agbekele ‘fe Baba wa;
On our father’s love relying, Jesu nfun wa l’ohun gbogbo
Jesus every need supplying, Ni yiye tabi ni kiku;
Then in living or in dying Ko le si nkan.
All must be well.
Amin.
18. HALLELUJAH CHORUS
18. ORIN ALLELUIA
19. BENEDICTION
19. ORE-OFE
Order of Photograph
Couple With:
Officiating Ministers
Both Parents
Bride’s Parent
Groom’s Parent
Bride’s Family
Groom’s Family
CAC Oke Anu Members
Bride’s & Groom’s Siblings
Bride’s Siblings
Groom’s Siblings
Bride’s & Groom’s Friends
Bridal Train
Bridesmaid &t Best Man
Maids of Honour & Men in Senator’s Attire
Bride Only
Groom Only
Couple Only
Little Bride
Bible Bearer
Bridal Train
Chief Bridesmaid. Best Man
ADEDEJI TITILAYO. ODEH
Little Bride. BIBLE BEARER
OGINNI OMOWONUOLA OCHE
Maids of Honour. Groom’s Men
ALL LADIES IN ASOEBI. ALL MEN IN SENATOR
ATTIRE
Vendors
Decorations
Catering
RAYO CATERING SERVICE
Reception Programme
1.Arrival of Guest
2.Introduction of Guest
3.Arrival of Couple
4.The Opening Prayer
5.Chairman’s Speech
.
6.Cutting of Cakes
7.Toast
8.Refreshment &t Music Toast
9.Couple Dance
10.Tossing of The Bridal Bouquet
11.Presentation of Gifts
12.Votes Of Thanks
13.Closing Prayer
14.Dance! Dance!! Dance!!
Notes
Notes